miércoles, 30 de julio de 2008

ORACION ;PADRE NUESTRO [YORUBA]





BABA wa ti mbe li orun
Ki a bowo fun oruko re
Ki ijoba re de
Ife tire ni ki ase li aiye
Bi won ti nse li orun
Fun wa ni onje ojo wa loni
Dari ese wa ji wa
Bi ati ndari ese wa ji wa
ti ose wa .Mafa wa sinu
idanwo.Suqbon qba wa lowo bilisi.
Amin

No hay comentarios: